# SignOfVictory
# Ni_Orukọ_Jesu.!
# Baba-alaini-Baba
Oluwa Iwọ ni mo Gbẹkẹmile...
Oh Lord, I put my trust in thee
Ọlọrun Anu oo, ṣanufunmi...
Oh Lord of Mercy, Have Mercy on me
Olugbala Oniṣẹ Iyanu, Yamilẹnu si rere...
The Lord of Wonders, surprise me wit Good wonders
Eleti gbaroye, Gbaroye mi
The Great Listener, Listen to my voice/Request
Ọba ti-un da-un Adura, Gbadura mi
The King that answereth prayers, answer my prayers
Ọlọrun Ijọ Aposteli ti Kristi, ma do ju Adura timi...
Olorun Ayodele Babalola, tẹti si oun ẹbẹ mi...
Nitori-pe;
Iwọ nikan lọba awọn Ọba,
Alagbada ina,
Ọba Atẹ-rẹ-rẹ kari-aye,
Ọlọrun Ife,
Ọlọrun Alanu,
Ọba tiki-sun,
Ọba tiki-ṣa
Ọba tiki-ku,
Alagbara Gi-ga-ga,
Ọba Atayerọ bi Agogo,
Araba nla tẹnikan o le ṣi-nidi,
Oke nla tenikan o le bi-wo,
Ọlọrun Alagbara,
Olorukọ nla-nla-nla,
Ẹlẹda gbogbo Aye,
Iba fun Ọba to jẹ lori gbogbo Ọba,
Iyin yẹ ọ Eledumare,
Kaaabiyesi rẹ ooo...
Iwọ nikan lo-go-ye,
Ọba to ku funmi, ki emi leba-ye,
Ọba to ji ya nitori mi, ki emi leba jọrọ,
Baba mi ọwọn,
Ololufemi ọwọn,
Olutojumi ọwọn,
Alanumi ọwọn,
Olutunumi ọwọn,
Moṣe Kaabiyesi si ọ..
Halleluyah.! To The Arugbo-Ọjọ...
HALLELUYAH...!!!!!
(AMIN)